Jóṣúà 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo wá fún yín ní ilẹ̀ tí ẹ ò ṣiṣẹ́ fún àti àwọn ìlú tí ẹ ò kọ́,+ ẹ sì ń gbé inú wọn. Ẹ tún ń jẹ àwọn èso ọgbà àjàrà àti àwọn èso igi ólífì tí ẹ ò gbìn.’+
13 Mo wá fún yín ní ilẹ̀ tí ẹ ò ṣiṣẹ́ fún àti àwọn ìlú tí ẹ ò kọ́,+ ẹ sì ń gbé inú wọn. Ẹ tún ń jẹ àwọn èso ọgbà àjàrà àti àwọn èso igi ólífì tí ẹ ò gbìn.’+