Jeremáyà 52:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ní ọdún kẹtàlélógún Nebukadinésárì,* Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ kó àwọn Júù lọ sí ìgbèkùn, àwọn èèyàn* náà jẹ́ ọgọ́rùn-ún méje ó lé márùndínláàádọ́ta (745).+ Lápapọ̀, ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (4,600) èèyàn* ni wọ́n kó lọ sí ìgbèkùn.
30 Ní ọdún kẹtàlélógún Nebukadinésárì,* Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ kó àwọn Júù lọ sí ìgbèkùn, àwọn èèyàn* náà jẹ́ ọgọ́rùn-ún méje ó lé márùndínláàádọ́ta (745).+ Lápapọ̀, ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (4,600) èèyàn* ni wọ́n kó lọ sí ìgbèkùn.