Nehemáyà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Gbogbo àwọn èèyàn náà kóra jọ ní ìṣọ̀kan sí gbàgede ìlú tó wà níwájú Ẹnubodè Omi,+ wọ́n sì sọ fún Ẹ́sírà+ adàwékọ* pé kó mú ìwé Òfin Mósè+ wá, èyí tí Jèhófà pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+ Nehemáyà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn àtọmọdọ́mọ Ísírẹ́lì wá ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lára gbogbo àwọn àjèjì,+ wọ́n dìde dúró, wọ́n sì jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti àṣìṣe àwọn bàbá wọn.+
8 Gbogbo àwọn èèyàn náà kóra jọ ní ìṣọ̀kan sí gbàgede ìlú tó wà níwájú Ẹnubodè Omi,+ wọ́n sì sọ fún Ẹ́sírà+ adàwékọ* pé kó mú ìwé Òfin Mósè+ wá, èyí tí Jèhófà pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+
2 Àwọn àtọmọdọ́mọ Ísírẹ́lì wá ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lára gbogbo àwọn àjèjì,+ wọ́n dìde dúró, wọ́n sì jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti àṣìṣe àwọn bàbá wọn.+