Léfítíkù 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Kó wá pa ewúrẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, tó jẹ́ ti àwọn èèyàn,+ kó mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sẹ́yìn aṣọ ìdábùú,+ kó sì fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ṣe ohun kan náà tó fi ẹ̀jẹ̀+ akọ màlúù náà ṣe; kó wọ́n ọn sí apá ibi tí ìbòrí náà wà, níwájú ìbòrí náà.
15 “Kó wá pa ewúrẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, tó jẹ́ ti àwọn èèyàn,+ kó mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sẹ́yìn aṣọ ìdábùú,+ kó sì fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ṣe ohun kan náà tó fi ẹ̀jẹ̀+ akọ màlúù náà ṣe; kó wọ́n ọn sí apá ibi tí ìbòrí náà wà, níwájú ìbòrí náà.