-
1 Kíróníkà 9:10-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Látinú àwọn àlùfáà, Jedáyà, Jèhóáríbù, Jákínì,+ 11 Asaráyà ọmọ Hilikáyà ọmọ Méṣúlámù ọmọ Sádókù ọmọ Méráótì ọmọ Áhítúbù, aṣáájú ní ilé* Ọlọ́run tòótọ́, 12 Ádáyà ọmọ Jéróhámù ọmọ Páṣúrì ọmọ Málíkíjà, Máásáì ọmọ Ádíélì ọmọ Jásérà ọmọ Méṣúlámù ọmọ Méṣílẹ́mítì ọmọ Ímérì 13 àti àwọn arákùnrin wọn, àwọn ni olórí agbo ilé bàbá wọn, ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún méje àti ọgọ́ta (1,760) ọkùnrin tó dáńgájíá tí wọ́n wà fún iṣẹ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́.
-