-
Nehemáyà 11:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Alábòójútó àwọn ọmọ Léfì ní Jerúsálẹ́mù ni Úsáì ọmọ Bánì ọmọ Haṣabáyà ọmọ Matanáyà+ ọmọ Máíkà látinú àwọn ọmọ Ásáfù, àwọn akọrin; òun ló sì ń bójú tó iṣẹ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́.
-