Nehemáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tó tẹ̀ lé Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì+ àti Jéṣúà+ nìyí: Seráyà, Jeremáyà, Ẹ́sírà, Nehemáyà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ṣemáyà, Jóyáríbù, Jedáyà,
12 Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tó tẹ̀ lé Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì+ àti Jéṣúà+ nìyí: Seráyà, Jeremáyà, Ẹ́sírà,