2 Kíróníkà 33:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, ó mọ ògiri ẹ̀yìn òde sí Ìlú Dáfídì+ lápá ìwọ̀ oòrùn Gíhónì+ ní àfonífojì títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ ó mọ ọ́n yí ká dé Ófélì,+ ó sì mú kí ó ga gan-an. Yàtọ̀ síyẹn, ó yan àwọn olórí ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi ní Júdà. Nehemáyà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.
14 Lẹ́yìn náà, ó mọ ògiri ẹ̀yìn òde sí Ìlú Dáfídì+ lápá ìwọ̀ oòrùn Gíhónì+ ní àfonífojì títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ ó mọ ọ́n yí ká dé Ófélì,+ ó sì mú kí ó ga gan-an. Yàtọ̀ síyẹn, ó yan àwọn olórí ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi ní Júdà.
3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.