ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 3:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Nígbà tí àwọn kọ́lékọ́lé fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì Jèhófà lélẹ̀,+ àwọn àlùfáà wọ aṣọ iṣẹ́ wọn, wọ́n mú kàkàkí+ dání, àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn àwọn ọmọ Ásáfù mú síńbálì* dání, wọ́n dìde dúró láti yin Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ìlànà tí Dáfídì ọba Ísírẹ́lì fi lélẹ̀.+

  • Ẹ́sírà 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí náà, àwọn èèyàn ò mọ ìyàtọ̀ nínú igbe ayọ̀ àti igbe ẹkún náà, torí igbe àwọn èèyàn náà ròkè débi pé àwọn tó wà ní ibi tó jìnnà réré ń gbọ́ igbe wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́