-
Ẹ́sírà 10:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Nígbà náà, àlùfáà Ẹ́sírà dìde, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ ti hùwà àìṣòótọ́ bí ẹ ṣe lọ ń fẹ́ àwọn obìnrin àjèjì,+ ẹ sì ti dá kún ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì. 11 Ní báyìí, ẹ jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ yín fún Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín, kí ẹ sì ṣe ohun tí ó fẹ́. Ẹ ya ara yín sọ́tọ̀ kúrò nínú àwọn èèyàn ilẹ̀ náà àti kúrò lọ́dọ̀ àwọn aya àjèjì.”+
-