Nehemáyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí Sáńbálátì+ ará Hórónì àti Tòbáyà + ọmọ Ámónì+ tó jẹ́ òṣìṣẹ́* ọba, gbọ́ nípa rẹ̀, inú wọn ò dùn rárá pé ẹnì kan wá láti wá ṣe ohun rere fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì.
10 Nígbà tí Sáńbálátì+ ará Hórónì àti Tòbáyà + ọmọ Ámónì+ tó jẹ́ òṣìṣẹ́* ọba, gbọ́ nípa rẹ̀, inú wọn ò dùn rárá pé ẹnì kan wá láti wá ṣe ohun rere fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì.