30 Mo wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò nínú gbogbo ohun àìmọ́ tó jẹ́ ti àwọn àjèjì, mo sì yan iṣẹ́ fún àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì, kálukú sẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀,+ 31 mo ṣètò bí wọ́n á ṣe máa kó igi wá+ ní àkókò tí a dá, mo sì tún ṣètò bí wọ́n á ṣe máa kó àkọ́so èso wá.
Ọlọ́run mi, jọ̀wọ́ rántí mi sí rere.+