-
Nehemáyà 3:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Lẹ́yìn rẹ̀, Hananáyà ọmọ Ṣelemáyà àti Hánúnì ọmọ kẹfà tí Sáláfù bí tún ẹ̀ka míì ṣe.
Lẹ́yìn rẹ̀, Méṣúlámù+ ọmọ Berekáyà ṣe iṣẹ́ àtúnṣe níwájú gbọ̀ngàn òun fúnra rẹ̀.
-