Nehemáyà 12:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ẹgbẹ́ akọrin ọpẹ́ kejì gba òdìkejì* lọ, èmi àti ìdajì àwọn èèyàn náà sì tẹ̀ lé wọn, lórí ògiri lókè Ilé Gogoro Ààrò+ títí dé orí Ògiri Fífẹ̀+
38 Ẹgbẹ́ akọrin ọpẹ́ kejì gba òdìkejì* lọ, èmi àti ìdajì àwọn èèyàn náà sì tẹ̀ lé wọn, lórí ògiri lókè Ilé Gogoro Ààrò+ títí dé orí Ògiri Fífẹ̀+