2 Sámúẹ́lì 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Hírámù+ ọba Tírè rán àwọn òjíṣẹ́ sí Dáfídì, ó kó igi kédárì + ránṣẹ́, ó tún rán àwọn oníṣẹ́ igi àti àwọn oníṣẹ́ òkúta tó ń mọ ògiri sí Dáfídì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé* fún Dáfídì.+ Nehemáyà 12:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.
11 Hírámù+ ọba Tírè rán àwọn òjíṣẹ́ sí Dáfídì, ó kó igi kédárì + ránṣẹ́, ó tún rán àwọn oníṣẹ́ igi àti àwọn oníṣẹ́ òkúta tó ń mọ ògiri sí Dáfídì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé* fún Dáfídì.+
37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.