Ẹ́sítà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ keje, nígbà tí wáìnì ń mú inú ọba dùn,* ó sọ fún Méhúmánì, Bísítà, Hábónà,+ Bígítà, Ábágítà, Sétárì àti Kákásì, àwọn òṣìṣẹ́ méje tó wà láàfin tí wọ́n jẹ́ ẹmẹ̀wà* Ọba Ahasuérúsì fúnra rẹ̀,
10 Ní ọjọ́ keje, nígbà tí wáìnì ń mú inú ọba dùn,* ó sọ fún Méhúmánì, Bísítà, Hábónà,+ Bígítà, Ábágítà, Sétárì àti Kákásì, àwọn òṣìṣẹ́ méje tó wà láàfin tí wọ́n jẹ́ ẹmẹ̀wà* Ọba Ahasuérúsì fúnra rẹ̀,