ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sítà 4:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ ọba àti àwọn èèyàn tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ abẹ́ àṣẹ ọba ló mọ̀ pé, tí ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí bá wọlé lọ bá ọba ní àgbàlá inú+ láìjẹ́ pé ọba pè é, òfin kan ṣoṣo tí wọ́n máa tẹ̀ lé ni pé: Kí wọ́n pa onítọ̀hún; àyàfi tí ọba bá na ọ̀pá àṣẹ wúrà+ sí i ni kò ní kú. Ó sì ti tó ọgbọ̀n (30) ọjọ́ báyìí tí wọn ò tíì pè mí sọ́dọ̀ ọba.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́