Ẹ́sítà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọjọ́ yẹn, Ọba Ahasuérúsì fún Ẹ́sítà Ayaba ní ilé Hámánì,+ ọ̀tá àwọn Júù;+ Módékáì sì wá síwájú ọba torí pé Ẹ́sítà ti sọ bó ṣe jẹ́ sí òun.+
8 Ní ọjọ́ yẹn, Ọba Ahasuérúsì fún Ẹ́sítà Ayaba ní ilé Hámánì,+ ọ̀tá àwọn Júù;+ Módékáì sì wá síwájú ọba torí pé Ẹ́sítà ti sọ bó ṣe jẹ́ sí òun.+