Ẹ́sítà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ rẹ̀ tó gbà lọ́wọ́ Hámánì, ó sì fún Módékáì. Ẹ́sítà sì fi Módékáì ṣe olórí ilé Hámánì.+
2 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ rẹ̀ tó gbà lọ́wọ́ Hámánì, ó sì fún Módékáì. Ẹ́sítà sì fi Módékáì ṣe olórí ilé Hámánì.+