-
Ẹ́sítà 6:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí náà, Hámánì sọ fún ọba pé: “Ní ti ọkùnrin tó wu ọba pé kó dá lọ́lá, 8 jẹ́ kí wọ́n mú ẹ̀wù oyè+ tí ọba máa ń wọ̀ àti ẹṣin tí ọba máa ń gùn, kí wọ́n sì fi ìwérí ọba sí orí ẹṣin náà.
-