-
Ẹ́sítà 9:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Módékáì+ kọ àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí sílẹ̀, ó sì fi àwọn lẹ́tà ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn Júù tó wà ní gbogbo ìpínlẹ̀ abẹ́ àṣẹ Ọba Ahasuérúsì, àwọn tó wà nítòsí àti àwọn tó wà lọ́nà jíjìn. 21 Ó sọ fún wọn pé kí wọ́n máa pa ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Ádárì àti ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà mọ́ lọ́dọọdún,
-