Ẹ́sítà 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pe àwọn ọjọ́ náà ní Púrímù, látinú orúkọ Púrì.*+ Nítorí gbogbo ohun tí wọ́n kọ sínú lẹ́tà yìí àti ohun tí wọ́n rí nípa ọ̀ràn yìí àti ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wọn,
26 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pe àwọn ọjọ́ náà ní Púrímù, látinú orúkọ Púrì.*+ Nítorí gbogbo ohun tí wọ́n kọ sínú lẹ́tà yìí àti ohun tí wọ́n rí nípa ọ̀ràn yìí àti ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wọn,