-
Jẹ́nẹ́sísì 41:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Fáráò wá bọ́ òrùka àṣẹ tó wà lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì fi sí ọwọ́ Jósẹ́fù. Ó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀* tó dáa fún un, ó sì fi ẹ̀gbà wúrà sí i lọ́rùn.
-