Ẹ́sítà 9:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, ìyẹn oṣù Ádárì,*+ nígbà tí ó tó àkókò láti mú ọ̀rọ̀ ọba àti òfin rẹ̀ ṣẹ,+ ní ọjọ́ tí àwọn ọ̀tá àwọn Júù ti dúró dè láti ṣẹ́gun wọn, ọ̀tọ̀ lohun tó ṣẹlẹ̀, àwọn Júù ṣẹ́gun àwọn tó kórìíra wọn.+
9 Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, ìyẹn oṣù Ádárì,*+ nígbà tí ó tó àkókò láti mú ọ̀rọ̀ ọba àti òfin rẹ̀ ṣẹ,+ ní ọjọ́ tí àwọn ọ̀tá àwọn Júù ti dúró dè láti ṣẹ́gun wọn, ọ̀tọ̀ lohun tó ṣẹlẹ̀, àwọn Júù ṣẹ́gun àwọn tó kórìíra wọn.+