-
Ẹ́sítà 8:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nínú ìwé náà, ọba fún àwọn Júù tó wà ní gbogbo ìlú kọ̀ọ̀kan láyè láti kóra jọ, kí wọ́n sì gbèjà ara* wọn, kí wọ́n pa àwọn ọmọ ogun àwùjọ tàbí ti ìpínlẹ̀* èyíkéyìí tó bá gbéjà kò wọ́n, títí kan àwọn ọmọ kéékèèké àti àwọn obìnrin, kí wọ́n run wọ́n, kí wọ́n pa wọ́n rẹ́, kí wọ́n sì gba ohun ìní wọn.+ 12 Ọjọ́ kan náà ni kí èyí ṣẹlẹ̀ ní gbogbo ìpínlẹ̀ tó wà lábẹ́ àṣẹ Ọba Ahasuérúsì, ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, ìyẹn oṣù Ádárì.*+
-