Ẹ́sítà 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn asáréjíṣẹ́ tó ń gun ẹṣin àfijíṣẹ́ tó wà fún iṣẹ́ ọba sáré jáde lọ kíákíá gẹ́gẹ́ bí ọba ṣe pa á láṣẹ. Wọ́n sì tún gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*
14 Àwọn asáréjíṣẹ́ tó ń gun ẹṣin àfijíṣẹ́ tó wà fún iṣẹ́ ọba sáré jáde lọ kíákíá gẹ́gẹ́ bí ọba ṣe pa á láṣẹ. Wọ́n sì tún gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*