Ẹ́sítà 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọba wá nífẹ̀ẹ́ Ẹ́sítà ju gbogbo àwọn obìnrin yòókù lọ, ó sì rí ojú rere àti ìtẹ́wọ́gbà* rẹ̀ ju gbogbo àwọn wúńdíá yòókù. Torí náà, ó fi ìwérí* ayaba sí i lórí, ó sì fi í ṣe ayaba+ dípò Fáṣítì.+
17 Ọba wá nífẹ̀ẹ́ Ẹ́sítà ju gbogbo àwọn obìnrin yòókù lọ, ó sì rí ojú rere àti ìtẹ́wọ́gbà* rẹ̀ ju gbogbo àwọn wúńdíá yòókù. Torí náà, ó fi ìwérí* ayaba sí i lórí, ó sì fi í ṣe ayaba+ dípò Fáṣítì.+