ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sítà 3:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Wọ́n wá pe àwọn akọ̀wé ọba+ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní. Wọ́n kọ+ gbogbo àṣẹ tí Hámánì pa fún àwọn baálẹ̀ ọba, àwọn gómìnà tó ń ṣàkóso àwọn ìpínlẹ̀* àti àwọn olórí àwùjọ èèyàn lóríṣiríṣi, wọ́n kọ ọ́ sí ìpínlẹ̀* kọ̀ọ̀kan ní ọ̀nà ìgbàkọ̀wé tirẹ̀ àti sí àwùjọ àwọn èèyàn kọ̀ọ̀kan ní èdè wọn. Wọ́n kọ ọ́ ní orúkọ Ọba Ahasuérúsì, wọ́n sì fi òrùka àṣẹ ọba gbé èdìdì lé e.+

  • Ẹ́sítà 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Kí wọ́n fi ẹ̀dà lẹ́tà náà ṣe òfin fún ìpínlẹ̀* kọ̀ọ̀kan, kí wọ́n sì kéde rẹ̀ fún gbogbo èèyàn, kí wọ́n lè múra sílẹ̀ de ọjọ́ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́