Jẹ́nẹ́sísì 6:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìtàn Nóà nìyí. Olódodo ni Nóà.+ Ó fi hàn pé òun jẹ́ aláìlẹ́bi* láàárín àwọn tí wọ́n jọ gbé láyé.* Nóà bá Ọlọ́run tòótọ́+ rìn.
9 Ìtàn Nóà nìyí. Olódodo ni Nóà.+ Ó fi hàn pé òun jẹ́ aláìlẹ́bi* láàárín àwọn tí wọ́n jọ gbé láyé.* Nóà bá Ọlọ́run tòótọ́+ rìn.