-
Jóòbù 42:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nítorí náà, Élífásì ará Témánì, Bílídádì ọmọ Ṣúáhì àti Sófárì ọmọ Náámà lọ ṣe ohun tí Jèhófà sọ fún wọn pé kí wọ́n ṣe. Jèhófà sì gbọ́ àdúrà Jóòbù.
-