-
Jóòbù 5:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ màá mú ọ̀rọ̀ mi tọ Ọlọ́run lọ,
Ọlọ́run sì ni màá gbé ẹjọ́ mi lọ bá,
9 Sọ́dọ̀ Ẹni tó ń ṣe àwọn ohun ńlá àtàwọn ohun àwámáridìí,
Àwọn ohun àgbàyanu tí kò níye.
-
-
Jóòbù 11:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ká ní o lè múra ọkàn rẹ sílẹ̀ ni,
Kí o sì na ọwọ́ rẹ sí i.
-
-
Jóòbù 22:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Tí o bá pa dà sọ́dọ̀ Olódùmarè, wàá pa dà sí àyè rẹ;+
Tí o bá mú àìṣòdodo kúrò ní àgọ́ rẹ,
-