-
Jóòbù 11:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Bí ọwọ́ rẹ bá ń ṣe ohun tí kò dáa, mú un jìnnà,
Má sì jẹ́ kí àìṣòdodo kankan gbé inú àwọn àgọ́ rẹ.
-
-
Jóòbù 11:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ayé rẹ máa mọ́lẹ̀ ju ọ̀sán gangan lọ;
Òkùnkùn rẹ̀ pàápàá máa dà bí àárọ̀.
-