-
Sáàmù 75:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí ayé àti gbogbo àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ yọ́,
Èmi ni kò jẹ́ kí àwọn òpó rẹ̀ yẹ̀.” (Sélà)