Jẹ́nẹ́sísì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọlọ́run ṣe orísun ìmọ́lẹ̀ ńlá méjì, èyí tó tóbi á máa yọ ní ọ̀sán,+ èyí tó kéré á sì máa yọ ní òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀.+
16 Ọlọ́run ṣe orísun ìmọ́lẹ̀ ńlá méjì, èyí tó tóbi á máa yọ ní ọ̀sán,+ èyí tó kéré á sì máa yọ ní òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀.+