Jeremáyà 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ‘Bí o bá tiẹ̀ fi sódà* wẹ̀, tí o sì lo ọṣẹ púpọ̀,Ẹ̀bi rẹ yóò ṣì jẹ́ àbààwọ́n níwájú mi,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. Málákì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Àmọ́ ta ló máa lè fara da ọjọ́ tó máa wá, ta ló sì máa lè dúró nígbà tó bá fara hàn? Torí òun yóò dà bí iná ẹni tó ń yọ́ nǹkan mọ́ àti bí ọṣẹ+ alágbàfọ̀.
22 ‘Bí o bá tiẹ̀ fi sódà* wẹ̀, tí o sì lo ọṣẹ púpọ̀,Ẹ̀bi rẹ yóò ṣì jẹ́ àbààwọ́n níwájú mi,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
2 “Àmọ́ ta ló máa lè fara da ọjọ́ tó máa wá, ta ló sì máa lè dúró nígbà tó bá fara hàn? Torí òun yóò dà bí iná ẹni tó ń yọ́ nǹkan mọ́ àti bí ọṣẹ+ alágbàfọ̀.