Jóòbù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ni Sátánì bá jáde kúrò níwájú* Jèhófà, ó sì fi eéwo tó ń roni lára*+ kọ lu Jóòbù láti àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀ títí dé àtàrí rẹ̀.
7 Ni Sátánì bá jáde kúrò níwájú* Jèhófà, ó sì fi eéwo tó ń roni lára*+ kọ lu Jóòbù láti àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀ títí dé àtàrí rẹ̀.