Jóòbù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí mo bá tiẹ̀ jàre, mi ò ní dá a lóhùn.+ Mi ò lè ṣe ju pé kí n bẹ adájọ́ mi* pé kó ṣàánú mi.