Jóòbù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ máa ń se àsè ní ilé wọn lọ́jọ́ tó bá yàn.* Wọ́n máa ń pe àwọn arábìnrin wọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta pé kí wọ́n wá bá wọn jẹ, kí wọ́n sì jọ mu.
4 Ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ máa ń se àsè ní ilé wọn lọ́jọ́ tó bá yàn.* Wọ́n máa ń pe àwọn arábìnrin wọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta pé kí wọ́n wá bá wọn jẹ, kí wọ́n sì jọ mu.