Jóòbù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bí ìkùukùu tó ń pa rẹ́ lọ, tó sì wá pòórá,Ẹni tó lọ sí Isà Òkú* kì í pa dà wá.+ Sáàmù 115:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn òkú kì í yin Jáà;+Bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú ìdákẹ́jẹ́ẹ́ ikú.*+ Àìsáyà 38:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo sọ pé: “Mi ò ní rí Jáà,* àní Jáà ní ilẹ̀ alààyè.+ Mi ò ní wo aráyé mọ́,Tí mo bá wà lọ́dọ̀ àwọn tó ń gbé ibi tí gbogbo nǹkan ti dáwọ́ dúró.
11 Mo sọ pé: “Mi ò ní rí Jáà,* àní Jáà ní ilẹ̀ alààyè.+ Mi ò ní wo aráyé mọ́,Tí mo bá wà lọ́dọ̀ àwọn tó ń gbé ibi tí gbogbo nǹkan ti dáwọ́ dúró.