Jẹ́nẹ́sísì 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Háránì kú nígbà tí Térà bàbá rẹ̀ ṣì wà láàyè, ní ilẹ̀ tí wọ́n ti bí i, ní Úrì+ ti àwọn ará Kálídíà.+
28 Háránì kú nígbà tí Térà bàbá rẹ̀ ṣì wà láàyè, ní ilẹ̀ tí wọ́n ti bí i, ní Úrì+ ti àwọn ará Kálídíà.+