Jóòbù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọlọ́gbọ́n ni,* ó sì ní agbára gan-an.+ Ta ló lè ta kò ó, tí kò ní fara pa?+ Dáníẹ́lì 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Dáníẹ́lì sọ pé: “Ẹ yin orúkọ Ọlọ́run títí ayé,*Torí òun nìkan ló ni ọgbọ́n àti agbára.+