Dáníẹ́lì 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+
21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+