Jeremáyà 14:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bí mo bá jáde lọ sínú pápá, tí mo sì wò,Àwọn tí idà pa ni mò ń rí!+ Bí mo bá sì wá sínú ìlú,Àwọn àrùn tí ìyàn fà ni mò ń rí!+ Nítorí wòlíì àti àlùfáà ti lọ káàkiri ní ilẹ̀ tí wọn ò mọ̀.’”+
18 Bí mo bá jáde lọ sínú pápá, tí mo sì wò,Àwọn tí idà pa ni mò ń rí!+ Bí mo bá sì wá sínú ìlú,Àwọn àrùn tí ìyàn fà ni mò ń rí!+ Nítorí wòlíì àti àlùfáà ti lọ káàkiri ní ilẹ̀ tí wọn ò mọ̀.’”+