-
Sáàmù 10:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jèhófà, kí nìdí tí o fi dúró lókèèrè?
Kí nìdí tí o fi fara pa mọ́ ní àkókò wàhálà?+
-
-
Sáàmù 13:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Jèhófà, ìgbà wo lo máa gbàgbé mi dà? Ṣé títí láé ni?
Ìgbà wo lo máa gbé ojú rẹ pa mọ́ fún mi dà?+
-
-
Sáàmù 44:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Kí ló dé tí o fi fojú rẹ pa mọ́?
Kí ló dé tí o fi gbàgbé ìyà tó ń jẹ wá àti ìnira tó bá wa?
-