3 Jèhófà sì bi Sátánì pé: “Ṣé o ti kíyè sí Jóòbù ìránṣẹ́ mi? Kò sí ẹni tó dà bíi rẹ̀ ní ayé. Olódodo àti olóòótọ́ èèyàn+ ni, ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú. Kò fi ìwà títọ́ rẹ̀ sílẹ̀ rárá,+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé o fẹ́ sún mi+ láti pa á run láìnídìí.”