ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 13:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Bojú wò mí, kí o sì dá mi lóhùn, Jèhófà Ọlọ́run mi.

      Tan ìmọ́lẹ̀ sí ojú mi, kí n má bàa sun oorun ikú,

  • Jòhánù 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó fi kún un pé: “Lásárù ọ̀rẹ́ wa ti sùn,+ àmọ́ mò ń rìnrìn àjò lọ síbẹ̀ kí n lè jí i.”

  • Ìṣe 7:59, 60
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Bí wọ́n ṣe ń sọ òkúta lu Sítéfánù, ó bẹ̀bẹ̀ pé: “Jésù Olúwa, gba ẹ̀mí mi.” 60 Lẹ́yìn náà, ó kúnlẹ̀, ó sì fi ohùn líle ké jáde pé: “Jèhófà,* má ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn lọ́rùn.”+ Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó sùn nínú ikú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́