8 Ó yá, ẹ mú akọ màlúù méje àti àgbò méje, kí ẹ lọ bá Jóòbù ìránṣẹ́ mi, kí ẹ sì rú ẹbọ sísun fún ara yín. Jóòbù ìránṣẹ́ mi sì máa gbàdúrà fún yín.+ Ó dájú pé màá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ pé kí n má fìyà jẹ yín nítorí ìwà òmùgọ̀ yín, torí ẹ ò sọ òtítọ́ nípa mi, bí ìránṣẹ́ mi Jóòbù ṣe sọ òtítọ́.”