Jóòbù 4:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wò ó! Kò ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì ń wá àṣìṣe àwọn áńgẹ́lì* rẹ̀.19 Mélòómélòó wá ni àwọn tó ń gbé ilé alámọ̀,Tí ìpìlẹ̀ wọn wà nínú iyẹ̀pẹ̀,+Tí wọ́n rọrùn láti tẹ̀ rẹ́ bí òólá!*
18 Wò ó! Kò ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì ń wá àṣìṣe àwọn áńgẹ́lì* rẹ̀.19 Mélòómélòó wá ni àwọn tó ń gbé ilé alámọ̀,Tí ìpìlẹ̀ wọn wà nínú iyẹ̀pẹ̀,+Tí wọ́n rọrùn láti tẹ̀ rẹ́ bí òólá!*