-
Jóòbù 8:11-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ṣé òrépèté lè dàgbà níbi tí kò sí irà?
Ṣé esùsú* lè dàgbà láìsí omi?
12 Nígbà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń rú yọ, tí wọn ò tíì já a,
Ó máa gbẹ dà nù ṣáájú gbogbo ewéko yòókù.
-