Jóòbù 13:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀ ń fi irọ́ bà mí lórúkọ jẹ́;Oníṣègùn tí kò wúlò ni gbogbo yín.+ 5 Ká ní ẹ lè dákẹ́ láìsọ nǹkan kan ni,Ìyẹn ì bá fi hàn pé ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n!+ Jóòbù 19:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ìgbà wo lẹ ò ní mú ọkàn mi* bínú mọ́,+Tí ẹ ò ní fi ọ̀rọ̀+ fọ́ mi sí wẹ́wẹ́? 3 Ìgbà mẹ́wàá yìí lẹ ti bá mi wí;*Ojú ò tì yín láti fọwọ́ tó le mú mi.+
4 Ẹ̀ ń fi irọ́ bà mí lórúkọ jẹ́;Oníṣègùn tí kò wúlò ni gbogbo yín.+ 5 Ká ní ẹ lè dákẹ́ láìsọ nǹkan kan ni,Ìyẹn ì bá fi hàn pé ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n!+
2 “Ìgbà wo lẹ ò ní mú ọkàn mi* bínú mọ́,+Tí ẹ ò ní fi ọ̀rọ̀+ fọ́ mi sí wẹ́wẹ́? 3 Ìgbà mẹ́wàá yìí lẹ ti bá mi wí;*Ojú ò tì yín láti fọwọ́ tó le mú mi.+